Job 2:1

Ìdánwò Jobu lẹ́ẹ̀kejì

1Ó sì tún di ọjọ́ kan nígbà tí àwọn ọmọ Ọlọ́run wá síwájú Olúwa, Satani sì wá pẹ̀lú wọn láti pe níwájú Olúwa.
Copyright information for YorBMYO